TOJU IWA RE ORE MI : Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n'ile eni, Ewa a si ma si l'ara enia, Olowo oni 'nd’olosi b'o d'ola. Okun l'ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l'o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ni de sare’e. Owo ko je nkan fun ni, Iwa l'ewa omo enia. Bi o l'owo bi o ko ni’wa nko? Tani je f'inu tan e ba s'ohun rere? Tabi ki o je obirin rogbodo; Ti o ba jina si'wa ti eda nfe, Tani je fe o s'ile bi aya? Tabi ki o je onijibiti enia; Bi o tile mo iwe amodaju, Tani je gbe'se aje fun o se? Toju Iwa re, ore mi, Iwa ko si, eko d'egbe; Gbogbo aiye ni 'nfe 'ni t'o je rere. (ENGLISH TRANSLATION) Enhance your character, my friend; Prosperity may depart from one’s home, Beauty may retreat from the body, And today’s rich could become poor tomorrow. Prosperity is like ocean surf; and wealth is an ocean wave, They come and go from one’s home as they Pleases, But, only good character foll...
Breaking News... Relationship..Lifestyles.. Sports... Politics...Gossips. This Is home for the news you crave for!